L'oke ati petele
L'oke ati petele
Nibe la gbe bi mi si o,
Ibe la gbe tomi dagba o,
Ile ominira
Emi yo fi abeokuta shogo,
Ma duro lori olumo,
Mayo loruko egba o
Emi omo lisabi.
Mayo mayo mayo ooo,
Lori olumo
Mayo mayo mayo ooo,
Lori olumo
Abeokuta ilu egba
Nko ni gbagbe re,
Nko ni gbagbe re,
Bi ilu odo oya.
Emi yo fi abeokuta shogo,
Ma duro lori olumo,
Mayo loruko egba o
Emi omo lisabi.
Mayo mayo mayo ooo,
Lori olumo
Mayo mayo mayo ooo,
Lori olumo
Artist: Aimee Mann
Artist: Marque
Artist: Chocolate Genius
Artist: Sasha